Ìdí tí mo fi fẹ́ gbé Babangida lọ ilé ẹjọ́ lórí ìwé tó kọ - Falana
Ọpọ eeyan lo si n rọ ero wọn lori iwe ti olori orilẹede Naijiria tẹlẹri, Ajagun fẹyinti Ibrahim Babangida kọ nipa ara rẹ to pe...
Read MoreWọ́n gbé gbogbo àwọn obínrin lọ - Àwọn obìnrin tí wọ́n fipá bá lò pọ̀ lọ́gbà ẹ̀wòn DR Congo sọ ìrírí wọn
"O sọ fun mi pe ti mo ba gbiyanju lati salọ, oun ma pami." Pascaline, 22, ranti ọrọ ọkunrin to fi ipabalopọ ninu ọgba ẹwọn Goma,...
Read MoreẸ̀mí sùn, ọ̀pọ̀ dúkìà ṣòfò níbi ìjàmbá tánkà agbépo àti tírélà n'Ilorin
Ẹmi sun, ọpọ dukia si ṣofo nibi ijamba ọkọ to sẹlẹ ni opopona mọrosẹ Oko-Olowo si Jebba ni ilu Ilorin, nipinlẹ Kwara....
Read MoreÀwẹ́ Ramadan: Wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nínú àgọ́ ara rẹ lásíkò tí ò ń gba àwẹ̀
Lọdọọdun ni ẹgbẹlẹgbẹ miliọnu awọn musulumi maa n gba awẹ fun ọgbọnjọ lasiko Ramadan. Fun bii ọdun meloo bayii ni awẹ...
Read MoreEnd of content
No more pages to load