Èyí lohun tíjọba sọ nígbà tí mo dá mílíọ̀nù púpò tí mo rí he padà - Muibi Shonubi
"Lẹyin ti mo da obitibiti owo ti wọn gbagbe sinu ọkọ mi pada fawọn ọlọpaa, mi o le rin lọja, lẹnu iṣẹ tori iha awọn araalu to...
Read MoreÌdí tí mo fi fẹ́ gbé Babangida lọ ilé ẹjọ́ lórí ìwé tó kọ - Falana
Ọpọ eeyan lo si n rọ ero wọn lori iwe ti olori orilẹede Naijiria tẹlẹri, Ajagun fẹyinti Ibrahim Babangida kọ nipa ara rẹ to pe...
Read MoreWọ́n gbé gbogbo àwọn obínrin lọ - Àwọn obìnrin tí wọ́n fipá bá lò pọ̀ lọ́gbà ẹ̀wòn DR Congo sọ ìrírí wọn
"O sọ fun mi pe ti mo ba gbiyanju lati salọ, oun ma pami." Pascaline, 22, ranti ọrọ ọkunrin to fi ipabalopọ ninu ọgba ẹwọn Goma,...
Read MoreỌpọlọ ọkùnrin tí iná jó títí tó fi ku, paradà di gíláàsì
Lẹyin nnkan bii ẹgbẹrun ọdun meji gbako ti ọkunrin kan ku ninu ina fokano, awọn onimọ ijinlẹ ti ṣawari pe ọpọlọ rẹ ti di...
Read MoreẸ̀mí sùn, ọ̀pọ̀ dúkìà ṣòfò níbi ìjàmbá tánkà agbépo àti tírélà n'Ilorin
Ẹmi sun, ọpọ dukia si ṣofo nibi ijamba ọkọ to sẹlẹ ni opopona mọrosẹ Oko-Olowo si Jebba ni ilu Ilorin, nipinlẹ Kwara....
Read MoreEnd of content
No more pages to load